Posts

Showing posts from July, 2017

ITAN IGBESI'AYE D.O FAGUNWA NI EDE YORUBA

ITAN IGBESI'AYE D.O FAGUNWA (1903-1963).        Daniel Olorunfemi Fagunwa je onkowe litireso no ede yoruba, won bi lodun 1903,nilu oke-igbo nipile ondo,D.O FAGUNWA losi ilewe st.luke's school,oke-igbo,ondo. osi tun losi ile eko giga st.andrew's college,oyo. o bere ise olukoni ni odun 1938.     Fagunwa si ni onkowe litireso akoko ni ede yoruba ti osi tun ma nlo imo ikoko (folk philosophy) ninu iwe re to bako..Lara awon iwe re toko ni:- Ogboju Ode Ninu Igbo Irunmale eyi toko ni odun 1938,eyi ti Ojogbon Wole Soyinka se eda re si ede geesi ni odun 1968, Eyi to pe ni (The Forest Of a Thousand Of Daemons), Igbo Olodumare 1949,Ireke Onibudo 1949,Irinkerindo Ninu Igbo Elegbeje 1954,Adiitu Olodumare 1961, D.O Fagunwa si gba ami eye (award) lodun 1955 ti won pe ni (The Margaret Wrong Prize),ti osi tun je omo egbe The British Empire ni odun 1959,fagunwa si ku lojo kesan,osu kejila odun 1963.